AYAJO KI AWON ENIYAN MARANTI WA FUN ANU 💯
ao ko eyo Atare si Atelewo 9 mesan fun Okunrin,7 mejee fun Obirin,ao fi enu yasi nigba 3 meta
Adura Re. aki mo odi ile de afefe,aki mo yara de era,Omode meji ki bawon gun iyan koro,agba meji ki bawon rin gbedeke wo Oja,Owe baba mi kan ni,Owe baba mi kan lailai ko,Owe Olodumare ni,ati erimi ni ati erimi ni,ati ewa mi ni ati ewa mi ni,Oro ti ema fi gbe ire aje Nlanla wa funmi ni ki ema so nipami,ki egbe ire wami ri,ki efi ire wami kan,Omode,agba,Obirin,Okunrin,ki efi ire aje sanu funmi. ao wa da atare yi si enu,ao maje,ao wa di ori wa mu,ao ma se adure titi ti ao fije tan lenu
No comments:
Post a Comment