ASIRI OSE IWE ODO EKAN OGBESE KAN BARAWAJU π―
Igbe Esin die,ao gun mo ose iwe ekan soso,ose ti oba wuwa ni o,ao fi le ori kanhinkanhin ibile tuntun,ao lo we ni Odo tohun San. ao koju si ibi ti odo na ti San bo,ao ko eyin si ibi ti odo na San lo,ikoko Ajere kekere ni ao fi ma bu omi si ara wa titi ao fiwe ose yi tan,ao mu kanhinkanhin ti ale ose mo yi dani ki ato bere si ni we,ao fi epo pupa pa gbogbo ara gbogbo
ADURA RE: Ere ti aja ba fi Ogun Odun sa,irin faji ni fun esin o,gbogbo ohun ti awon egbe mi ti fi Ogun Odun se seyin,ti won ti fi Odun kan se seyin,ti won ti fi Ose kan se seyin,ni ki Emi Lag. Omo Lag. ni ki ma fi ose kan se,ki ma fi Ojo kan se,ao ma we ose yi ti aba ti we tan,ao wa ju kanhinkanhin yi si eyin pelu ikoko Ajere yi na danu opari
IKILO PATAKI: ikoko Ajere ti fi Ewe Akoko Oojo tabi Ewe iyalode ff tabi pp ati otin ibile tabi Omi fo inu ati eyi re lati le yo Owo Oja kuro lara re
No comments:
Post a Comment