NKAN IFOWO FUN OJA TITA TABI ISE LATI LE MARI CUSTOMER DADAA 💯
ISENA RE.
Ewe taba gbigbe die,Ose eyikeyi,eyo Omo atare 21
SISE RE.
Ao gun gbogbo re papo yio kuna daadaa,ao ma fi fo owo wa sinu ike kan,ao wa da Omi ifowo yi si titi iwaju ibi ti atin sise tabi taja. ao ma fifo inu shop wa na,Pelu Ogo lodo Olorun,ese ki da ni titi,ese awon eyan koni da lodo re lati wa ra ohun ti onta. Ise yi kere loju sugbon ata to Iyo dun ni
No comments:
Post a Comment