Friday, October 6, 2023

OSE AWENU AMUBO,IKORIRA,PROMISE AND FAIL 💯

 OSE AWENU AMUBO,IKORIRA,PROMISE AND FAIL 💯 


Fun iwo tobafeki iseyi sisefun o bami share iseyi sinu opolopo group Miran kiwonleje afanibe kodefi comment rese adura funmi like kolejefun e 


ISENA RE.

Iru woro die,Eru inu aro(ashes)die,Ito idiwa idaji 

SISE RE.

Ao gun iru woro leyin na,ao tun gun eru inu aro mo,ao wa po mo ose dudu tabi ose eyi ti o ba wuwa,ao pin ose yi sinu kahin kahin meta. Ao wa fi ito idaji pa gbogbo arawa latoke dele kia to we ose yii,ao we kahin kahin akoko ni aro,ekeji osan eketa ale,ao ma fi ito tia to laro para kia to ma we ose yi oo. ose yii daju gan pupo fun eniti amubo mandalamu tabi ikorira bahun dalamu,ati promise and fail


Fun ibere lori iseyi abi Lori isemiran abi Lori oro igbesi aiyere abi Lori ogun todajuko ee call or whatsapp https://wa.me/+2349022547429

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...