ASIRI OBA AGADAGODO TO GBONA JANJAN TI A LE FI GBA NKAN NLA LOWO ENIKENI TI ENI YEN KO SI NI WADI RE MO RARA KODA A TUN LE FI TI OJO ABI GBA OWO NLA LOWO CLIENT 💯
ISE NARE. Ao wa Ori pepeye ati ese pepeye ti ko lanu,ewe alupaida ff die,iye agbe1 kan,iye aluko 1 kan,ikoode 1 kan,ewe inaa pupa die Agadagodo 1 kan,odindin atare 1 kan,ewe rekureku die,irun iyamopo die,ao bu die lara erupe ogiri alapa tola nu die
SISE RE. ao jo gbogbo awon eroja yi papo mora won pelu odidi ataare kan,ao fi eje oga po ise yi,ao wa bu ebu die sinu owu akese,ao wa ran ni owu imule,ao di mo eyin AGADAGODO yen,ao wa di ni owu dudu ati funfun,ao tun ro ebu die sinu iho AGADAGODO yen,ao wa fi sekeseke si niwaju,ao fi eemu si leyin,ao wa fi aba kan mo Ara ogiri ti a ba ti fe lo,ao pe ohun re si
OHUN RE. asifo ni tagbe,asifo ni ti aluko,asifo ni tagbe, asifo ni ti aluko, sekeseke mu,aaba mu,Tori eemu kan ki mu irin ti ni agbede,aba kan ko gbodo ba nkan ti(ao so oun ti aba fe lo fun)ao wa tu ataare si ao wa ti pa
AKIYESI PATAKI
ASIRI YI WA NILE BAYI BAYI FUN TITA
IF YOU WANT TO ORDER MY PRODUCTS?
YOU HAVE ANY QUESTIONS ON WHAT WE POST
OR YOU NEED HELP ON ANY SPIRITUAL PROBLEM OR WAR THAT YOU ARE FACING CALL OR whatsapp https://wa.me/+2349022547429
No comments:
Post a Comment