Friday, October 6, 2023

AWURE AJIGBOWO πŸ’―

 AWURE AJIGBOWO πŸ’― 

Ewe Efinrin Iworomoba wewe Oojo tutu die,Ewe Aladun ti amo si Ewuro Oojo tutu die,ao gun papo mo Ose eyi ti oba wu wa dandan,ao ko sinu ike ff Olomolori 1kan,ao fo odidi eyin ororo ibile ti o mo dada meta mo ati epo eyin re,ao lo imi orun ti mo si imi Ojo die mo,ao depa gbe pamo fun 6 mefa,leyin  Ojo kefa ao ma we 5:00 tabi 6:00 lararo kutukutu ki ato lanu soro si enikeni,ale ma fi kanhinkanhin 1kan we ti  ao fi lo ose yi tan ko je dandan ibile eyi ti aba ti ri

IKILO PATAKI:idi ose yi kogbodo kanle,ike ff Olomolori 1kan,ti fi Ewe Akoko Oojo tabi Ewe iyalode ff tabi pp ati otin ibile tabi Omi fo inu ati eyi re lati le yo Owo Oja kuro lara re,

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY πŸ’―

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY πŸ’―  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...