Friday, October 6, 2023

OSE EYONU ITAJA 💯

 OSE EYONU ITAJA 💯

Ewe Emiesu ti amo si Rerinkomi Oojo ododo ff ori re nikan ni ama ja die,ko nidi Ewe ori re,Epo iginla gbigbe tabi tutu die,Eru Alamo die,ao gun po mo ose eyi ti oba wuwa dada,ao ko sinu ike ff Olomolori 1kan,ao ma we lararo kutukutu 5:00 to 6:00 idaji ki ato lanu soro si enikeni,ale ma fi kanhinkanhin 1kan we ti ao fi lo ose yi tan ko je dandan ibile eyi ti aba ti ri

IKILO PATAKI: ale gbo ododo ff ori re yi na Lia fi omi si iwon ba omi ti oba jade nibe,ao ta die sinu Lofinda Divine Grace kekeke tabi nla 1kan,ao lo epo iginla gbigbe die,eru Alamo die,ao ma ta sara jade,idi ose ati lofinda yi kogbodo kanle,ike ff Olomolori 1kan,ti fi Ewe Akoko Oojo tabi Ewe iyalode ff tabi pp ati otin ibile tabi Omi fo inu ati eyi re lati le yo Owo Oja kuro lara re

No comments:

Post a Comment

CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...