Monday, June 20, 2022

OLUWA TI SE OHUN GBOGBO FUN IPINNU RE 💯

OLUWA TI SE OHUN GBOGBO FUN IPINNU RE 💯 

ISENBAIYE

√1. Ti Abafe We Ose E Mama Jeki Ama Wo Bata We!
√2. Gbogbo Ogun Ti Aba Nse Ema Jeko Mawa Ninu Iyara Ti Atin Ba Obiri Ni Ajosepo
√3.Ka Jina Si Biba Obirin Lajo Sepo Lati Eyin Tabi Ki Obirin Wani Oke
√4. Leyin Ti Aba Ni Ajosepo Tan Ao Gbodo Fi Owo Kan Ogun Kankan
√5. Owo Ti Afin Se Ise Ao Gbodo ma kibo oju ara obinrin-Finger Obirin
√6.Leyin Ojo Keta Ti Aba Lajosepo Tan Aye Wa Funwa Lati Fowo Kan Ogun
√7.Efi Ojo Meta Tabi Merin Sile Teba Se Ogun Tan Kie To Sunmo Obirin
√8.Ki Obirin Oni Isun Eje,Mase Fowo Kan Ise Wa Tabi Wo Ibi Ti Anko Ogun Si
√9.Olo Ti Abafinlo Nkan Eje Ki Ama Fi Ewe Rinrin Ati Ewe Safara Pelu Epin Fo Oju Olo Na Nu Nigbakugba
√10. Ti Aba Njo Any Ise Lowo Ki Ama Sa akiasi redada Kio Maba Foo Tio Bati Fo Koni Sise Mo
√11.Tia Aba Njo Ise Aje Ki Ama Fi Epo Yi Idi Reka
√12. Ti Abanjo Ogun Lowo Ki A Ma Fi Epo Obo Si Egbe Aro Idana Wa
√13.Ti Aba Nlo Ise Lowo Ao Gbodo Mafi Omo Olo Si Lori Ni Igbati Aba Dawo Duro
√14. Kia Ato Dawo Le Ise Kankan E Je Kia Ma Se Aluwala,Tabi Kia Ya Omi Si Mimo Ki Afi San Oju AtiEse Pelu Owo Wa
√15. Omi Ti Aba Fi Fo Aso Ao Gbodo Fi Fo Bata Ese Wa Kokin Jeki Ise Dahun
√16. Ose Ti Obiri Bafi Weku Nba Ise Je Lara
√17. Ao Gbodo Fi Ose Ti Afi Fo Aso Ku We

IWULO EPO OBO 💯

 IWULO EPO OBO 💯 

Ebamikalo.

(1) ao lo epo obo ti yio kunna,ao da sinu omi toba loworo(togbona die)lowuro kutukutu,ao fi we pelu ose tobawu wa(ki owo aje matewa)
(2) epo obo lilo,pelu iyo ati eru inu aro,ao po mo ose,ao mafiwe(arobi)ao gba epo pupa lori ina,tiobati gbona dada,ao da epo obo ti atilosi,ofarabale kogbona dada, ao yo epona,epo obo towanibe ao po mose ao mafiwe,ao si mala epo na(eyonu)
(3) epo obo,ata ijosi 
(4) ao gun pomo ose dudu,ao mafiwe fun jometa meta.(fun ibere ontoruwaloju)
(5) ao gba epo obo ninu epo pupa,ao da epo pupa na sinu mis paris,holy michael,bintu,eyokookan,ao mafi para,epo obo toku ni isale kokona, ao pomo ose
ao mafiwe(fun eyonu awon agba)



IWULO AGBON FUN ILOSIWAJU ATI IFOKANBALE NINU AYE TODAJU DAADAA 💯

IWULO AGBON FUN ILOSIWAJU ATI IFOKANBALE NINU AYE TODAJU DAADAA 💯 

 MOJUBA LOWO  OBA TONI EWE ATI EGBO

AGBON JE ESO KAN TI ELEDUMARE DA PELU ARAMONDA LATARI OMI TOWA NINU RE .GBOGBO INKAN TI ELEDUMARE DA PATAPATA KO MON BI OMI SE DE INU AGBON .IDI NIYI Ti AWON EYAN FII PE OMI AGBON NI AWAMARIDI.

GBOGBO ISE  YII 100% CONFIRM NIO. IWO TOBA SE AFOJUDI IWO LOMO .👇

ALAKALA PELU OWU ALANTAKUN

ao ra HOLY MICHEAL PERFUME eyokan,BACK TO SENDER PERFUME eyokan,pelu omi inu AGBON odidi kan ao wa MIX re papo daadaa. ao ma fi perfume yii sara ati inu yara wa(AO RI AWON EROJA YII NI SPIRITUAL(PLACE OWU ALANTAKUN ATI ALAKALA YII YOLO PATAPATA ✔

ASIRIBIBO OWO 

Agbon odidi kan toni omi ninu daadaa pelu ewe akoko oojo,ao da omi agbon yii sinu abo kan ao wa fi omi yii gbo ewe akoko yii. leyin igba taba gbotan,ao wa fi ase ko gbogbo idoti kuro nibe. ao wa fii #1000 Tuntun kan sinu omi yii fun bi wakata merin leyin wakati yii. ao daniyan Owo sinu omi yii. ao gbemu lekansoso,ao wa lona Owo yii si BANKII TABI ILE ITAJA NLA KAN(DAN ASIRI YII WO NI IBERE OSU.TITI OSU YII AFI PARI APOWA KONI GBE FOWO)✔


IFERAN GBOBO AYE

ao fii omi agbon gbo ewe ominsinminsin pelebe oojo .ao gun agboku re ati epo obo mon ose lux ao mix omi tagbo mon missparis perfume ,ao ma fi ose we aoma fi missparis para(GBOGBO AYE NIYO MA NI IFE WA DANWO) ✔


AJEPO MORAN MOJELE(poison)

ao fi omi agbon gbo ewe ewuro ao wa fi din eyin ibile kan je lepo niyo ,ao so aseje yii sori ewe BOMUBOMU  aoje aseje yii laisoro si eda kankan  . BI ABAJE MOJELE GBOGBO RE LAOPO LESEKESE ( GBIYANJU SISE RE NI OSU MERUN MARUN ✔✔

IWULO ITO(URINE)IDI WA FUN IWOSAN ARAWA LORISIRISI ONA 💯

IWULO ITO(URINE)IDI WA FUN IWOSAN ARAWA LORISIRISI ONA 💯 

1_ Imule ife :- e fi ito idaji bo igbin titi ti ito yen a fi gbe mo igbin na lara lai jona rara, ki e din igbin na ninu epo pupa ti e ba ti bo tan, lehina ao fun enina je.

2_Arun oju :- Ema kan ito yin si oju na laro ati lale.

3_ Fun eniti o nfi oju ko owu alantakun :- Ao fi owo alafia wa gba ito ti aba koko to ni owuro ki a to ba enikeni soro, ao fi ito bo oju ati ori wa, ao fisile sibe to bi iseju 10 -- 15 ki a to fo nu

4_Fun okunrin ti ato (sperm) re ko ba lolu tabi tiko le fun iyawo re loyun

:- Ki iru okunrin be ma mu ito iyawo re, ki iyawo na si ma mu ito oko re ni cup kekere kan laro ati ni ale fun osu meta ni agbara Olorun Iru okunrin bee yio di alagbara tio tayo awon elegbe re ife oun ati iyawo re yoo si lagbara gidigidi ju ti atehinwa lo, koni soro fun lati fun eyikeyi obinrin loyun pelu.

5_Kokoro ara lfo, Eela, :- Ki oluwa re mafi ito idi ara re para laro ati lale

6_ So agba di ewe (ajidewe)

Agbalagba toba le mu ito idi re ni glass cup kekere kan laro ati lale, ki o si mafi ito diedie pa gbogbo ara re koto sun lale, egungun re a maa le ni nigbogbo igba ti yoo si dabi ara odo, gbogbo aisan to le ma dagba lamu ko le nipa lori re (o daju)

7_ Egbo adaajina :- Ki eniti o ba ni egbo na ma fi ito idi ara re fo oju egbo na lemeta lojumo,

ki o si ma mu diedie ninu ito na

8_ APORO OFA TABI FUN ENI TOJE NKAN LOJU ORUN TABI ENI TI NKAN OLORO BUJE

Ao gba ito ti a koko to ni idaju lai ti soro si eda olorun kankan . 

SISERE. Ao to ito yen sinu cup kan E o bu iyo gidi sibi kan sinu ibikan ao fi iyo na te ifa eji ogbe ao pe ofo resi ao wa da iyo na sinu po ao wa gbe

cup ito (urine) yen ao fi sibi ro Kosi bi nkan na se le lagbara to walahi eni na yio po tabi ya mon igbe jade ayafi ti won ba gbe unkankan sibi ikun na loku.

OFORE... Bi a ba fi iyo senu, ojo na ni oro iyo n mun enu 3* bi ito ba kanle, oro ito a munle 3* gbogbo owo awon

ota lara Emi LOL ki oro ito mun jade, gbogbo nkan buruku to wa lara emi LOL Ki oro iyo mun jade lowo ki o ba mi ti ejiogbe ni mofi ise yi ran, gbera ki o ran won jade.

Lagbara Olorun ti o da aye ati orun,koda bi won ba ta eni na lofa yio po tabi ya jade lyo gidi ni o lyo gidi ti won ma n fi agolo won sinu ora ni ooo

OSE BIBO ASIRI TODAJU SAKA 💯

OSE BIBO ASIRI  TODAJU SAKA 💯 

Isena re 

👉Efo gure.

Ose lux tabi joy meji (2).

Kafura pelebe. Idi kan.

👉Sise re. Ao han gbogbo ewe efo gure yen laisi igi tabi ododo kankan nibe ao gun po mo ose lux tabi joy meji,ao ko sinu ike funfun Olomori. Ao wa gun kafura pelebe idikan loto. Ti aba ti gun kafura yen tan ao wa kosi lori,ao wa fi owo(hand)wa ropo daada

👉Lilo re ao ma fi we laaro kutuhai.

Odaju gan ni o

AROBI/ASETA 

ao fi iso tuntun lu oju agbon kan,a o wa ko omo atare 42 si enu a o je kuna,a o mu omi agbon yen si pelu adura pe gbogbo eni toban dimi lowo ise rere ki oro re o dojuru,ti aba mu omi tan,ao fo agbon danu.


 OSE AWURE/ITAJA 

Ewe ominsinminsin gogoro, ewe abamonda,oga aye kan, ikode 3,ao gun gbogbo re papo ti yio kunna daada,ao fi ose poo, ao wa fi lofinda bintu kan po ose naa,a mafiwe larolaro.


 IFERAN OBINRIN CUSTOMERS OBINRIN

 Ileke segi,efun, osu,Ileke tun, Ileke ifa,ao gun po,ao da sinu lofinda. Ao mafi pa oju ati owo, ara.


AWEBI WEPE DANU

 Ao lo wa epo obo die ao gun mo ose dudu pelu ewe bomubomu ao lo fi we lodo lekan soso.


TURARI ITUWO TO DAJU

 Ewe ajekobale,igi oro onigege, epo obo,a o gun po,a o wa sa,ti o ba gbe tan,a o wa ma fi fi turari sile wa ni aro ati ale.


ISEGUN IKORIRA ATI IFERAN 

 Ao ka psalm 150, 71, 7times,sinu omi agbon,ati igo bintu kan pelu awe ojo kan ao wa mix omi agbon ati bintu papo. ao ma kan sinu omi iwe,ati ipara. odaju awon eniyan yoo ma feran wa...ikorira yoo si dagbere fun ooo


OGUN INANRUN TODAJU

Egbo gbogbonse,egbo ipeta,egbo ifon,egbo agbasa,egbo legunoko,egbo tude,egbo inabiri,eepo konunkoho,eepo igi opele,baaka,alubosa elewe,isu alubosa,ata wewe pupa,imi ojo dudu,atare16,kanhun,fofo okun,iyere,jankaawo,eeruawola,aidan tio ba ni isu daadaa,ao gun gbogbo repo,ao maa fi mun eko gbigbona

BI OLE BA JI INKAN WA

 Ogun to ole ba ji nkan wa a o wa obi alawe meta 2 a o fi gbadura ki ole ti o ji nkan wa yen da pada atipe ki asiri re ko tu dandan a o wa lo fi obi naa ta awon alagbe lore(ikan fun alagbe okunrin ikan fun alagbe obirin) loba pari odaju pe asiri ole na yoo tu tested work ni o


OGUN OKIKI

Akere tio pe, akuko adie kan,eye owiwi kan ,ori akuko ati ori owiwi,ati akere ni ao lopo tiyio kunna dada ao pomo ose dudu,ao mafiwe.

Ofore. Mawi mawi nise eye owiwi,owiwi loni ki won mawi mi kaye (Aniyan),Toripe akere nijuwe ibiti odo wa (Aniyan),akuko nijuwe Ilu ki omoaraye majuwe mi si dada. Ao mafi ose na we


ÀLÁ LILA ÀTI ÌTUMỌ 💯


ÀLÁ LILA ÀTI ÌTUMỌ 💯 


Oludamọran fún ọrọ aiye wa níí ala lila jẹ bẹ sini bíi eda koba mura síi ọrọ aiye oseese kii owa bakanna 


Bíi obalala pe oun Lu Agogo  níí ojú ala tii agogo yẹn kọwa dun sita 

Ìtumọ:- igbiyanju Onitoun ko ti to kii onitoun tẹra mọ adua 


Sugbon bíi Agogo náà baa dún jade 

Ìtumọ:- Onitoun yóò gbo iroyin ayọ laipe 


Bíi eyan ba ríi ọmọ ọlọ níí ojú ala 

Ìtumọ:- Onitoun yóò ṣe àṣeyọrí lori Adawole 


Bíi obalala pe oun gbe ọmọ pọn loju ala.

Ìtumọ:- gbàdúrà kii omase ríi idamu. 


Bíi oba ùn wẹ fún ọmọ loju àlá tii o de síi in w'oju Olohun fún ọmọ

Ìtumọ:- kii onitoun gbàdúrà kii ati bimo mase jẹ ìnira 


Bíi obalala pe won fún ee níí bundle owó 💰 níí oju ala.

Ìtumọ:- wa ríi oda owó tẹra mọ adua 


Bíi ọmọ ìkókó naya ìgbé síi ee lára níí ojú ala.

Ìtumọ:- wa ríi idunnu tabi kii ori nkan ayọ laipe 


Bíi obalala pe oun se weeding níí ojú ala níí gbogbo igba 

Ìtumọ:- gbàdúrà ọkọ orun tabi aya orun mase da irin ajo aiye ee ru.


Bíi owa wa ninu ojo loju ala 

Ìtumọ:- idaamu níí  kún fún adua 


  Bíi obalala pe oun gbo Radio 📻 loju àlá

Ìtumọ:- wa gbọ ìròyìn ayọ laipe kún fún adua 


Bíi obalala pe oun jẹ ọgẹdẹ 🍌 loju ala 

Ìtumọ:- wa ríi nkan iderun 


Bíi obalala pe ina 🔥 jo gbogbo nkan ini ee loju ala 

Ìtumọ:- gbàdúrà kii omase padanu nkan tii ogbè ọkan lè 


Bíi obalala pe phone ee sonu loju ala

Ìtumọ:- connection rere nla yóò bọ sonu kuro níí ọwọ ee 


Bíi obalala pe oun jẹ akara loju 

Ìtumọ:- awọn agbalagba 🦅 yóò mú ifaseyin ba ee 


Bí obalala pe owa ninu ọja owa fẹ ra ẹran tutu 

Ìtumọ:- ṣọra kii omaba fii ọwọ arare fa ifasehin sinu aiye ee .


Bíi obalala níí gbogbo igba pe owa níí ìhoho loju 

Ìtumọ:- asiri Onitoun koni bọ kún fún adua 


Bíi obalala pe ọrẹ gba bàtà níí ẹsẹ ee loju ala 

Ìtumọ:- nkan lara awon ọrẹ ee yo gba ololufẹ mọ ee lọwọ.


Bíi oba wọ aṣọ pupa loju ala

Ìtumọ:- ìṣẹgun wa fún ee kunfun adua 


Bíi obalala pe won fún ee níí ounjẹ jẹ nii party tii Iwọ náà síi jẹ 

Ìtumọ:- lara awon tii osunmo yóò sọ ee dii ẹni ẹyin


Bíi obalala pe won síi fila kuro níí ori ee tabi Ose fila kuro lori eniyan 

Ìtumọ:- gbàdúrà kii won mase  gba ogo aiye ee danu 


Bíi obalala pe owa ninu Motor Motor yen wa ùn pada seyin.

Ìtumọ:- hummmmm gbàdúrà kii omase ríi àpadà síi aburu


Bíi obalala pe owa pẹlu awọn ile friend tii Iwọ ati won jọ se kékeré loju àlá 

Ìtumọ:- ikolo re yóò padà besini gbàdúrà kii ọta mase sọ ee dii ẹni ẹyin.


Bíi obalala pe oun gbon òwu alantakun 🕸️ loju àlá 

Ìtumọ:- eleda ee tii n ba  ṣẹgun ijakule 


Mogbadura fún gbogbo ẹyin témi pe Aiye koni fii ogo wa rare


Ọlọrun koni jeki afi ọwọ ara wa se ara wa

Ki Olorun siju anu wo gbogbo wa 

GBIYANJU KO NI  IWE 

ASIRI IRAWO EDA LOWO

GBÌYÀNJÚ LATI SE ÀWÁRÍ ARA-RE KII OMABA WÁYÉ ASÁN



ETO AWORO ALANU FUN WOLI,ALFA,TABI ONISE OWO 💯

ETO AWORO ALANU FUN WOLI,ALFA,TABI ONISE OWO 💯 

Ise Nare. Ajesi Orun Adie Ibile toni Agbado ninu kan,Ewe Anu die,Ewe Sawerepepe die,Ewe Atewogbare die,Eru Alamo die

Sise Re. Ao lo gbobo  re pomo arawon,ao pomo Ose Eyikeyi ti o ba wu wa,ao ko Ose na sinu ikoko Ajere,ao mafiwe lararo pelu.

Psalm Re. Ojojumo ni Ajesi adiye mangba alejo ki Emi L.Omo L. gbalejo Olowo loni,Sawerepepe lobami pe Olore ati alanu mu wa loni,Ewe Atewogba loni kintwo migba Owo Nlanla loni,Eru lobamiru won wa towotowo Owo(hand)won,Ona kona lomi ngba wonu Ajere,Ona kona nikingba ri alanu tiyi ofi Owo Nlanla sanu mi loni


 ASEJE BASIRI OWO  

ewe rinrin  oojo,panmo dudu tagesi 16,iru Pete,iyere 16,ata ijosi 16,ikoko aseje titun,epo,iyo, 

SISERE. ao fi omi san ewe yen nu Tori erupe ara re,ao fi sile ki omi arare yen gbe,ao lo iyere ati ata yen po,ao wa ko ponmo yen sinu isasun,ao wa da ata ati iyere talo lelori,ao tun da iru si,ao wa gbo ewe yen laifomi si rara,Omi tojade lara ewe yen ao da sori ponmo yen ao se lepo niyo,ao so sori osuka aso funfun,ao se adura si ao je,ise yi yara mu owo wa kiakia,ejeka gbiyan jue wo

AWỌN ÀMÌ TI A FII ÙN MỌ ẸLẸGBẸ ỌMỌ 💯

AWỌN ÀMÌ TI A FII ÙN MỌ ẸLẸGBẸ ỌMỌ 💯 

MOFE GBEWA RINRIN AJO LATI SA KIESI SORO ARARE

Bíi ẹda kii ùn bá ùn se akiyesi lori lrin ajo aiye ee oseese kii ògo aiye wọn máṣe tẹsiwaju bẹ sini oseese kii Ami ikorira wa ninu aiye ee 

Nje wọn mọ pé ẹlẹgbẹ ọmọ níí ee ṣugbọn Aini àkíyèsí níí oun da duro.

Kii ùn se gbogbo ẹda alaye níí oun níí anfani lati ma ríi awọn  ẹlẹgbẹ rẹ ṣugbọn bíi oba ùn se awọn akiyesi wọn ẹlẹgbẹ ọmọ níí rẹ.

Gẹgẹ bí àpẹẹrẹ;

Bíi o ba saba ma ùn lala pé Irun ori ee gùn jù tii tẹlẹ lọ tabi òun ríi owó ẹyọ níí ori ee níí gbogbo igba ẹlẹgbẹ ọmọ ni ee

Bíi oba ùn ṣe àkíyèsí pé odabi pe eyan ma ùn dúró sí ee leyin níí gbogbo igba ẹlẹgbẹ ọmọ níí ee 

Bíi Ese 🦶 tabi ọwọ 👋 ba ùn dédé sun omi tètè mura ẹlẹgbẹ ọmọ ni ee.

Bíi aya obìnrin ba ùn dédé njà níí gbogbo igba 

Bíi oba saba ma ùn lala pé owá laarin awọn kékèké tii ẹjọ ùn sere tabi kọrin níí gbogbo igba.

Ẹlẹgbẹ ọmọ kii ùn fẹ duro síi eti odò nítorí ojú wọn yóò ma su

Tii oba nlala pe oun wo Asofunfun ninu ODO elegbe omo nii ee.

Bii eyinju  obinrin badabi eyinju Olongbo  elegbe omo ni ee tètè ma se fii ọrọ aiye tafala

Bii Inu ekan na  obinrin ba funfun laarin meji elegbe omo ni ee.

Bii Iwuwasi obinrin ba un yato nii gbogbo igba elegbe omo ni ee.

Ẹlẹgbẹ ọmọ kii ùn ríi òrun sun níí awọn akoko yii 

2:00 am si 3:00 am 

Idi niyi

*Àṣẹ wa níí arawọn níí ìgbàyen

*Awọn akoko yii níí agbara ma ùn wọ arawọn.

Etc.....

 *AWỌN ỌJỌ TI ODARA JU KII ẸLẸGBẸ ỌMỌ MA ṢE SÁÁRÁ TABI ÌPÈSÈ* 

Ọpọlọpọ ẹda nii oun sise bíi alaise bẹ sini Aini àkíyèsí lori irin Ajo aiye eda ènìyàn kii ùn jẹ kii ọna tètè la fún 

Ejeki amo iru eniti a jẹ kii aiye wa le tètè tẹsiwaju gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ Eyini ọjọ tii odara fún gbogbo eléré ọmọ lati ma se ìpèsè tabi saara fún ẹgbẹ wọn 

            EMERE OMI

Awọn iseda bayii kii ùn níí orí ọkọ bẹ sini ayé ma ùn yọnu sí wọn idi niyi ti won fii tètè ma ùn gba kadara tii ayan mo wọn.

K'odara kii iseda yìí máa jẹ ẹja aro 🐟 ti oba fẹ ríi ògo aiye ee lo 

Besini iseda yii nifẹ síi èkuru daada ọjọ ti odaraju fún wọn tii wọn lè má ṣe saara tabi ìpèsè  ni.

*SUNDAY TABI THURSDAY*

  *IRANSẸ ÀJÉ ATI IGI AJÉ* 

Alagbara omo nii Awon iransẹ àjé  tabi igi ajé jẹ  idi niyi tii WON kii unfibe bii omo pupo bẹ sini wọn tètè ma ùn bínú sí odi bẹ sini iseda wọn kò ni fesi inu bibi  awọn iseda yii nifẹ lati máa je ogede tabi ireke ojo tii odara fun won lati ma se ìpèsè tabi saara sinu odò níí 

  *THURSDAY TABI TUESDAY*

             *ALARAGBO* 

Awọn ipin iseda yii ko rírà kii okunrin tabi obinrin ma pa irọ fún wọn bẹ sini wọn tètè ma ùn ni igbọkanle ninu awon alabagbe won gbogbo ọmọ alaragbo nifẹ síi nkan eso ( fruit ) níí jíjẹ bẹ sini osepataki fún lati ma fii awọ funfun jẹun ojo odara ju fún wọn láti máṣe saara tabi ìpèsè ni

*WEDNESDAY TABI FRIDAY*

             *OMO OMI* 

pupo ninu awon edayii nii kodara kii won maje eja Aro nitoripe omo iya ee nii ounje sugbon Aini Akiyesi fun opolopo inu won nii oma unfa Gbese tabi Amubo oko funwon iseda yii ma ùn bẹrù láti losi odo bẹ sini bíi wọnyi ba ùn wẹ ninu baluwe wọn kii ùn tètè bọ ta boro 

Won ní fẹ síi omi púpọ ṣugbọn wọn kii ùn le duro síi eti odo 

Ojo tii odara kii won ṣe ipese tabi saara sinu Odo nii

   *TUESDAY TABI SATURDAY*

ÀMÌ BURÚKÚ NINU EBI 💯

ÀMÌ BURÚKÚ NINU EBI 💯 

Kii ọlọhun siju anu wo awa eda eniyan nitoripe ọpọlọpọ bẹni nii wàhálà ati idamu ùn dojú kọ ṣugbọn olohùn nikan ni ole b'awọn tán ìṣòro wọn pẹlu Àmì buruku yii wa ninu ọpọlọpọ ebi  bẹ sini latara Àlá lila Ami buruku yii ma ùn wọ inú Aye ẹdá 

Paapa julo ejeki  aso nipa Ami buruku yii tii owa ninu ebi gẹgẹ àpẹẹrẹ

*Nje iwọ Mope awọn iran kan wà toje pe won kii ùn nii owó lọwọ Ami yii kii unse ikan tii oba ojumu.

*Nje iwọ Mope ọpọlọpọ obìnrin nii ọjọ oriwon ti lo ṣugbọn wo kori okunrin ko enu ife siwọn bíi Ami buruku yii bawa lara obinrin kosi bíi osele rẹwa to koni lọkọ 

*Nje iwọ mọ pé awọn iran kan wà toje pe Ami Àìrí ile ọkọ gbe nii Ami buruku arawọn besini awọn òbí wọn kii nfẹ kii won nii ọkọ besini obi ẹlòmíràn nii Ami buruku tii ayé fi sí lára 

*Nje iwọ pé àwon ìdílé kan wà ti ojepe  wọn kii ùn lo ju 40 years lo nile ayé eyiti obalo koja 40 years ajepe omura síi ọrọ aiye ee ṣugbọn kii unsaba wọ pọ ninu ebi wọn 

*Nje iwọ Mope awọn idile kan wà tii wọn kii ùn lu Aluyo oun réré ni igbesi Ayé wọn òsì ati idamu nii ounjẹ wọn ipọnju ati wàhálà nii ayanmọ tiwọn 

*Nje iwọ mọ pé àwọn idile kan wà tii ojepe gbese nii kojeki ìlọsíwájú wọ inú  Aye wọn. Àmì buruku nii eleyi kaka kii wọn mura síi ọrọ Ayewon radarada nii wọn unba kiri 

*Nje iwọ Mope ninu eyin Mefa tii iya ati baba yin kosi eniti odani ₦5000 ninu bank account ee bẹ sini gbogbó eyin Mefeefa bi wọn ba kọ gbogbo yin jọ ekole ríi ₦20000 tu jọ lati fii ran àwọn òbí yín lọwọ hummmm Ami buruku nii eleyi kodara. 

*Nje iwọ mọ pé BODY ODOUR nii Ami buruku ti ayé gbé lé ee lọwọ

*Nje iwọ Mope Ọti mímú nii Àmì buruku ti ayé gbé lé lọwọ gbogbo awọn tii wonba fese lore  òrun ọti yii konile je kii wọn ràn e lọwọ

*Mouth ODOUR nii ÀMÌ buruku to unja ẹlòmíràn

*Ọpọlọpọ awọn irankan àmi buruku arawọn nii Aini Aya iru awon yii ma ùn nii owó lọwọ gan ṣugbọn obinrin kii bawon kalẹ 

*Ọpọlọpọ Akọbi Ọmọ nii Ami Buruku yii tiso di ẹni ẹyin

*Nje iwọ Mope Inú ilé bàbá ee tii òùngbẹ nii oun fa Ipọnju ati. Wàhálà sinu Aye ee.

*Nje iwọ Mope inu ilu baba ee  owa nii olórí ogún ti ounja Ayé ee.

*Gbigba kadara odi  gbọ olórí Ami buruku nii 

Gbìyànjú kii Ose adura nii oru ògànjó kii omaba waye asa: 

WAHALA ATI ADOJUKO IPO AKOBI OMO NINU EBII.

Opolopo Akobi omo oun sise bii Erin tii osi unjeje iliri kii olohun siju anuwo gbogbo Akobi omo 

Besini  opolopo obi nii otibaye Akobi ee je latara Oro enu.

Kodara kii awon obi feran omokan ju omokan lo ARISIKI tabi Ogo omo nii wonfii untafala nitoripe kosi eniti ofegbo pe Egbon awon fesorire ju owun lo tii Inu ee fedun sii 

      OKUNFA WAHALA SINU AYE AKOBI

*Kodara kii gbogbo Akobi maase Adehun pe ounfe segba see awo 

*Kodara kii Akobi MAA binu abiju kii omaba pada dii enii yepere

* Kodara kii Akobi gbokan le ogun awon Obi kii omaba dii eniyepere 

*Kodara koi akoba nii igbagbo ninu Adehun awon obi ee kii omapa pada dii ero eyin.

Nii OTITO gbogbo Ologo ati Asiwaju Omo ninu ebii nii oma un nii ogun sugbon kii olohun sinu Anu wo waaaa.

ÒGÚN TÍÌ NSỌ ÀWỌN AKỌBI DII ERO ẸYÌN*

Mogba ni Adura pe Gbogbo iwọ Akọbi nínú ilé yìí ọlọhun koni sọ rẹ di ẹrọ eyinì

Ọpọlọpọ akọbi loyeki otisẹ orire jubayi lọ ṣugbọn kádàrá rẹ tidi idakuda wonti la IGI AJÉ ilé wọn da ina.

Njẹ  iwọ mọ pé tí osaba ma ùn ríi awọn Apẹrẹ mefa yìí Ogun idile ndá rẹ láàmú.

Bíi saba ma ùn fi oju, ẹsẹ, ará kò jankariwo yala loju ala tabi ojú ayé 

Ìtumò:- Ifaseyin ati ijakule níí

Bíi obasaba ma ùn tọ sile (bed wet) níí ekan losu

Ìtumò:- wàhálà nifun iru akọbi yìí

Bíi obalala pe òun níí Ìbálòpọ̀ níí gbogbo igba loju ala lẹyìn náà ni owá bá Sperm nii Arare loju ayé

Ìtumò:- ogun ìdílé àti Ifaseyin, pelu Aya orun ni

Bíi promise and fail ba maunsaba wafun ee níí gbogbo Adawole  ee

Ìtumò :-Ogun Akọbi níí kunfun adua

Bíi kobasi akojọ lẹnu iṣẹ rẹ tí odese iwadi síi tii osije ọna ọlá rẹ níí iṣẹ náà.

Ìtumò:- ogun Ifaseyin nii 

ỌRINRIN àìsàn yìí ologo Akọbi ọmọ níí wọn má nfi daalamu nitoripe awon amokunseka kii nfẹ kii ògo aiye ee buyo

                         *Ìkìlọ*

Kodara kii akọbi ọmọ ma masturbate 

Ìtumò:- níí Gbogbo igbati Oba nṣe Ikan won yìí awọn Aburu 

Meta kankan amasele síi.

Koni síi iṣerere fún irú àwọn èèyàn náà

Koni leni Akojọ oun rere

Arawọn yóò maarun (body odour


DIE NINU AWON AKOBA TI OWA NINU OÚNJẸ OJU-ORUN

Nkan ibanuje nii ounjẹ oju orun je ọlọhun konije kii adi    ẹni ẹyin

Ọpọlọpọ ẹda ènìyàn níí oun koju iṣoro yìí ṣugbọn ko mọ ọnà abayọ bíi oti  lejepe orisirisii igbiyanju nii otise ẹlòmíràn tii na owó 💰  pa bo nii gbogbo ee ùn jasi

Púpọ ninu awọn alagbara aiye ma ùn fii òun jẹ jíjẹ loju orun fa wàhálà sinu aiye akọbi ọmọ kii won mase fii ẹni gíga ninu aiye bẹ sí í kii won mase ríi ogo wọn lo

Njẹ iwọ mọ pé OL'ogo ẹda ènìyàn níí oun ma ùn koju awọn iṣọrọ yìí. 

Gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ

Kii akọbi ọmọ máa tọ sile níí ekan tabi emeji kosi

Bíi kii wọn máa fi àìsàn WÁRÁPÁ dàn akọbi ọmọ wọ

Kii ẹnu mase to ọrọ láwùjọ

Ati bẹbẹ lọ.....

 *EYINI AWỌN NKAN TI OUNJE OJU ORUN MA UN FÀ SINU AIYE ẸNI* 

*OUNJE OJUORUN ma nsoni dii eni eyin nii gbogbo igba ọpọlọpọ ẹgbọn níí otidi àbúrò latara òun jíjẹ loju orun bíi ẹlòmíràn ba ùn sọrọ láwùjọ aiye koni Mope oun koju iṣoro nlánlá bayii 

*OUNJE OJUORUN níí okunfa ikorira sínú aiye awa eda eniyan bíi ee koba mura síi ọrọ aiye ee odidandan kii ọna ati jẹ atomu bosi ìnira fún.

*Oúnjẹ oju-orun nii oluranlowo fún ọrinrin ati owu alantakun nitori pe bíi iku ilé koba pani tii ode kólé ráyè pàá ènìyàn.

*OUNJE OJUORUN ma ùn fa idamu sinu aiye ẹda eniyan nítorí pé níí gbogbo igba níí gbese ati oda owó má ùn da ẹlòmíràn láàmú latara oúnjẹ oju-orun

*Oúnjẹ oju-orun nii okunfa promise and fail púpọ ẹda ènìyàn níí oun koju amubo ọkọ àti aya nitori pe gbogbo igba níí wọn má ùn je ùn loju orun

*Oúnjẹ oju-orun nii okunfa  opolopo Abiku  òòrè sinu Aiye Eda eniyan ọjọ ti ẹlòmíràn ba ti níí àdéhùn pẹlu eniti yóò sọ sinu ìgbèkùn ojo naa níí yóò lalá pé òun jẹun loju orun.

*Ounje ojuorun kí ùn  únjẹ́ kii opolopo Eda tete Debi tii oyeki ode ninu aye nítorí àṣeyọrí saba ma ùn jina síi iru wọn

*Oúnjẹ oju-orun orun níí okunfa wárápá sínú aiye ẹda eniyan oseese kii ọmọ jo'gun àìsàn yìí lọwọ àwọn òbí ee ṣugbọn latara oúnjẹ oju orun níí (báwo níí ẹda ṣẹlẹ bọ ninu wárápá)

*BAWONI ASELE BO LOWO OUNJE OJUORUN*

*Ṣọra fún àdéhùn sise pelu awọn ọrẹ ati mọlẹ bi 

*Ṣọra fún wiwọ aṣọ ti otako irawo rẹ sun 

*Ṣọra fún adisọkan lori adawole ee

*Máṣe sọrọ síi awọn agbalagba🦅

*Máṣe gba ogún ologun laye ninu aiye 

*Ṣe àwárí ilé tí òun gbé kii otoko síi inu ile náà kii ùn se gbogbo ile níí a ungba.

Ṣugbọn yatọ síi iru awon nkan wọn yìí ọna wo gangan nii alegbe bọ lọwọ nkan burúkú yii???

ỌLỌHUN KONI FIWA SILẸ FUN AYEMU

*OKUNFA AMU BỌ ỌKỌ FUN OBÌNRIN*

Púpọ nínú obìnrin nii oun dojuko ìṣòro yìí ṣugbọn diẹ nii inu wọn nii komope kii unse oju lasan nitori ọnà mẹta ni Amubo ma ùn gba wa aiye obinrin besini bíi àkóbá tete mu ojuto lati igba èwe olewu fún ọmọ nii ọjọ ọla gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ;

            *LATI ỌWỌ ÒBÍ*

OJA ọmọ kìí ùn ṣe oun ti afii unnsere besini kainkain ọmọ tuntun kii unse òun ti alefi máa tafala nitori pe bíi Alaboyun ba tosí orí ọja ọmọ tuntun kosi Aniani odidandan kii ọmọ yìí nii amubo ọkọ nii ọjọ ọla besini bíi wọn bá mú ite ati kainkain tii afii ùn wẹ ọmọ tii wọn jọ papọ mọ ibi omo tii wọn tún lo da sinu odo tii oun sàn odidandan kii obinrin nii Amubo ọkọ

                *AFOWOFA* 

Ọnà keji nii afowofa fún arawa nitoripe kosi bíi osele wun ko ri to ọlọhun da ọkunrin fún obìnrin kodesi eniti owa laye tii koni ọkunrin ti ee ṣugbọn bíi ako ati igberaga bati poju fún obìnrin odidandan kii ofi ọkọ ṣe boy friends besini iru wọn má ùn nii ìdádúró lori nini ọkọ high taste loso OBÌNRIN miran di eniti ọkunrin ùn gbeju sile 

Iwọ tii oun wa oni Benz's sugbon kìí sì nii ọkàn ee lati ba ọkunrin jeya kii ní aridaju pe oni Benz's yí óò fe óò gẹgẹ bíi aya púpọ nínú obìnrin nii oti fii akoko ee ṣofo ṣugbọn komo.

     *BII EDA BATI SII ESEGBE NII OWURO KUTUKUTU AIYE EE.* 

Opolopo Eda nii otisife nigba ewe ee tii wonti fii AMII sii Lara eleyii amajeki awon eyan magbe jusile kii unse pe Awon aye fii Seka fun biki basepe oti tii sii ESEGBE Sugbon bii olohun bafese Anu ee odidandan kii opade eniti yio ran lowo kuro ninu isoro bayii.

    *KAINKAIN OMO TUNTUN* *ATI ITE OMOTUNTUN* 

Opo Obi nii wonti fii Owo wan fa Amubo OKO TABI AYA sinu Aye omo won latara Fifi Inu tan ore friends nitoripe kodara kii  amafi KAINKAIN tii afiwe omo ikoko tabi ITE OMOTUNTUN tafala nitoripe won ma fii unse ISE IKORIRA SINU AYE EDA ENIYAN Eni BII aye bada ikorira sii EYAN Lara odidandan kii oma mu Amubo kosi boseleni Owo 💴 lowo to koniri oko tabi Aya tii yio fedi ojo Ale nitoripe wonti lo owun AMUSE AGBARA REE NIGBE IKOKO OOO.

         *EPE LATENU OBI* 

Pupo ninu obi nii oti fii enu Baye omo reje latara epe sise 

Gbogbo awon nkan wonyii kodara bii epe batibere sini jaa omo odidandan kii ikorira wonu iru Aye enibe Osile faa Amubo pelu.

                 BONUS 

Ti o ba la ala wipe O nba obirin sun loju orun ti sperm wa da jade ti a rare si wet,

ITUMO;- IFASEYIN IJAKUNLE PROMISE AND Fail nii iru ikan bayii manfa sinu aye Eda ...Adua ati Ise awon igbiyanju lafinsegun nkan bayi tori ise awon ota niyen

 Ti o ba la ala wipe o ba afesona re lopo loju orun

ITUMO:- Eo le fe arayin lailai o si gbodo fi agidi fe iru Obinrin be o lewu fun e mura si Adua daada ki o le ri Obinrin gidi

Ti o ba la ala wipe onigunnu nba e ja loju orun

ITUMO:- Ise awon ota inu ebi re ni mura si adua kiwon maba bori e

 Ti o ba la ala pe o fi umbrella ☔ bori loju orun

ITUMO:- Wari bibo asiri ati anu lodo Olohun mura si adua daada

MOGBALADURA PE AMUBO KONIJE TII EMI ATI IWO.

OOGUN TI OLE BA JI NKAN WA LO*

Ori alakedun, 

ata ijosin 9,

ewe Ina, 

ewe esisi, 

ewe aragba, 

ewe oloyin, 

ao lo awon ewe yipo

mo ose,

Ao fi di oju alakedun kan, 

ao lo ata ijosi pelu omi die ao je koki ao fi di ojukeji... 

Aofi igi kan gun nidi aogbe duro looro sigun yara... 

Ao wa eyo igbale mesan to gun dada eyiti won tifi gbaleri aodi bi osusu owo ao naro re si legbe.

OFORE: (ao ma je eyo atare mesan lenu, ao si tun mofi igbale ti adi yen malualakedun yen lori) Pelu sisope.... 

Afataboju kirojusoju, afoseboju kirojusoju, okualakedun kiroju jagbado, kankankan lewe inajo, warawara lomode toko esisi bo, ileogbaona o gba nise ewe aragba, ewe oloyin kipahun obarisaa da..... Enito gbe hun bayi

(aodaruko hunkan tiwon jilo yi) ki ile mogba ki ona magba.... Ayafi kowa dapada..... Ao wa

tu atare tan je lenu si ori alakedun yen.....

NOTE: ojo meta Pere ni ama fi se ise yen, onitohun maa daa pada.

OBINRIN

Pataki nii gbogbo awon obinrin he ninu aye AWA Eda bii okunrin bawa tii kosi obinrin ninu aye ee oseese kii odi Eni yepere lawujo.

Nje Iwo mo wipe ISUBU EE Loni Owo obinrin lotiwa

 Okunrin meji lowa ninu Aye gege bii Apere;

   OLOKUN ESIN/ FAWORAJA

OLOKUN ESIN je okunrin Tii Oni Ori obinrin pupo ninu won je AFINJU besini die ninu won  je Akinkanju omiran ninu won lema rewa( None Hanshome ) elomiran ninu won sile rewa( Handsome) besini obinrin ma npo funwon gan wonsije ONISINA Eda kosi Sugbon isubu won Owo obinrin lowa besini ORIRE WON Owo obinrin lowa pelu.

             *AKIYESI* 

*kii unse gbogbo obinrin nii eyan legun AYA EE  oseese kii OSII. Ta okunrin Tii obagun Ori obinrin imiran 

*Kii nse GBOGBO  obinrin tii obagbe OWO IFE wa nii ama nbasun kii aye ee Mase Baje 

*Kii unse gbogbo obinrin naa nii wonti lo Sugbon bii obaje emere elekisa oseese kii okunrin gun AYA EE kii aye okunrin naa Baje.

           *OKUNRIN ALAJE* 

IRU awon edabayii ma un nii OWO 💵 lowo gan Amo latara obinrin nii wonti nii owo gege bii eniti ofe ELERE OMO Sugbon ojoti obati lu ( fight ) with iyawo ojo yen nii OGO Aiye ee Titan 

Iruwon awon Okunrin bayii kii unsaba nii Ori obinrin bii wonba ko enu Ife sii obinrin awon Obinrin kii nfibe GBA funwon pupo ninu won nii Ayawon ma unja lati ba obinrin soro besini won nifesi MASTURBATE IKAN wonyii ma unle OORE ATI OLA kiro nii arawon nii 

Sugbon kosibi osele rito ALAJE obinrin nii won ma nri Fe gege bii iyawo besini leyin tii wonbati nii owo tan won ma nfe iyawo keji 

EYIN EYAN MI LOKUNRIN EJEKI AGBADURA KII AYEWA MASE BAJE 

BESINI KII AWANA SORA FUN IWA ELEGBIN ATI AGBERE.

ỌRỌ NÍPA ORI BIBO 💯

               ỌRỌ NÍPA ORI BIBO 💯 

Ori jẹ ùn kan pataki lati máa bọ bẹ síni ilọsiwaju wà fún gbogbo ẹnití òun bọ ori ee 
Kii ùn se gbogbo eyan níí nkan dudu tabi ogun ùn sise níí ara wọn nítorí pé gbogbo irawo kánkan ni oni nkan ti oba lara mu 
Njẹ iwọ mọ pé bíi nkan wọnyii ba ùn ṣẹlẹ sí ee odidandan kii o bọ òrí rẹ nítorí pé igbiyanju nii òun mu eni gaa láyé gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ
Bíi iṣẹ ko ba lọ dédé
Bíi gbese ba pọju fún ẹdá ènìyàn
Bíi idiwọ ọmọ bíbí ba ùn da eda ènìyàn láàmú
Bii alakala ba ùn pọju fún ẹdá ènìyàn
Bíi ipọnju ati IFASEHIN ba ùn ṣẹlẹ síi ẹni
Bíi kobasi ifọkanbalẹ lẹnu iṣẹ tabi níí idile ẹni
Bíi ogun ìdílé ba ùn da eday ènìyàn láàmú
Bíi èpè ba ùn jani
Bíi ẹda ko níí àṣeyọrí lori adawole ee 
Ọpọlọpọ ẹda ùn sise bíi ẹrin tii osi ùn jeje eleri ṣugbọn niwonba ìgbà tí obati bọ òrí é 
Ọpọlọpọ ẹda eniyan níí ko mọ pé ori òun níí oun takò owun lẹnu iṣẹ idi niyi tii kofi síi akojọ fún 
Púpọ ẹda nii oun gbé ìlú ti otako ori ee ṣugbọn anfani tii koni lati bo ori òun l'ofa wahala síi inú àiyé ee Logan tii obati bọ òrí odidandan kii eleda ee tètè lánàá fún 
Òwu alantakun 🕸️ tii fa ijakule sinu aiye ẹlòmíràn ṣugbọn logan tii obati bọ òrí ee odidandan kii wahala kuro ninu aiye ee 

                         ÌKÌLỌ
kii ùn se gbogbo eyan níí olebawa bọ ori wa 
Bíi ẹda koba bọ ori ee ni ona tii o to wahala ati ma wọ inú àiyé ee 
Bíi ẹda koba bọ ori níí ilana rere ijakule atun ma wọ aiye ee
Gbogbo eniti o bọ ori ee gbọdọ jẹ ninu  nkan ti won ba fi bọ ori yala 
Ẹja aro 🐟 gbigbe tabi tutu
Ṣugbọn ọmọ omi kogbodo je eja aro 🐟
Adìyẹ 
Ẹyẹ 🐦 ẹtù
Ewúrẹ 🐐
Ìgbín 🐌 ṣugbọn onirawo erupe kogbodo jẹ ìgbín
Obi 
Orógbó
Ati bẹbẹ lọ



   

AWỌN NKAN TI OTAKO GBOGBO IRAWO FUN ỌJỌ IBÍ NI ṢIṢE 💯

AWỌN NKAN TI OTAKO GBOGBO IRAWO FUN ỌJỌ IBÍ NI ṢIṢE 💯 

Ọpọlọpọ níí ohùn se nkan tii otako irawo ee bẹ sini kii ùn se pe o mọọmọ se nkan won yii a mọ Aini imo lori nkan tii irawo wọn ko fẹ níí okun fa nkan wọn yìí 

Aiyimoye eda níí o jẹ gbese tabi níí o wọ wahala leyin BIRTHDAY ti o ṣe nítorí pé òun ṣe nkan tii otako ipin iseda irawo ee ni 

Gẹgẹ bí àpẹẹrẹ.

             IRAWỌ AFẸFẸ

Níí gbogbo ọjọ ti irawo yìí bá fẹ ṣe birthday eyinì nkan tii kogbodo ṣe

Ṣọra fún ìjà

Mase jeki won da erupẹ síi ee

Ṣọra fún Ibalopọ níí ọjọ yìí.

Ṣọra fún àdéhùn sise níí ọjọ yìí.

           IRAWO INA

MONDAY

Omo TII ojo ibire baabo Sii ojoyi kii igbiyanju LATI Mase

Mu  oti  ( alcoholic)

mase jeki enikeni gba EE nii ORI 

NI suru nii ojo yii kii ojo ale ATI ojo Ola ee lebosi irorun

nii ojo yii nitoripe  Ifaseyin ojo ola NI ikanyi nfa.

TUESDAY

Mase would Aso dudu nii ojoyii kii wahala Mase wonu. Aiye. EE.

WEDNESDAY

Mase baa obinrin tabi OKUNRIN nii IBALOPO SEX nii ojoyii kii igbiyanju le sise ninu  Aiye EE.

THURSDAY

FRIDAY

MASE jeki wonda Omi Sii EE Lara kii wahala Mase SELE nii ojo yii

SATURDAY

SUNDAY

ojo yii nii Agbara gan fun iwo tii ojo ibire baabo sii ayajo yii tii otunje onirawo  Ina

Mase gbiyanju LATI wo Aso pupa ATI  fila pupa ounti odara ju fun EE Niki ogba Awe kii osimase gba enikeni laye LATI daa Omi Sii EE Lara notoripe iseda ree takoawom ikan wonyii.


               IRAWO OMI

MONDAY 

WEDNESDAY

Iwo tii ojo ibire baabo Sii ojoyii Mase daaba LATI pariwo Arare besini Mase gbiyanju LATI wo Aso dudu ATI Aso yellow eleyii tako iseda IRAWO EE besini kii omu inu OPOLOPO Eda eniyan dun nii ojo yii sugbon iseda ree kofeki oba enikeni jaa ( fa wahala ) nii ojo ibi ree ku ojometa kii Ifaseyin Mase wo inu aye EE.

THURSDAY

FRIDAY

SUNDAY

Oun tii oje ibanuje Nipe  eniti oje onirawo omi ti ojo ibire bosi inu Awon ojo yii  gba kii won da Omi idoti Sii owun NI ara Gbogbo eniti obase ikan wonyii yio fa Ifaseyin ATI Akoba fun iru OKUNRIN tabi OBINRIN tii ojo ibi EE bosi inu Awon ojo yii pelu afikun EYINI AWON ikan tii odara kii eniti ojo ibi re bosi Awon ojo yii Mase kii idunu lewo inu ayewon. 

Gbiyanju kii ogba Awe nii ojo yii.

Mase jeki enikeni gba ee nii Ori.

Mase lo Ata nii ojo yii.

Gbiyanju kii owo Aso FUNFUN nii ojoyii besini Mase binu nii ayajo yii kii wahala Mase SELE.

SATURDAY

GBOGBO onirawo omi ti ojo ibire baabo Sii ojoyii kii onitoun gbiyanju LATI pe apeje fun Awon agbalagba ATI Alabagbe EE kii ofi IYO (SALT) SE SAARA  nii owuro kutukutu kii wonto bere eto.


            IRAWO ERUPE

Kose maani nii Awon IRAWO yii je kosi owun tii wonkole see Gbogbo ojo ti birthday won baabo Sii sugbon kan soso nii  otako iseda won 

Wonkogbodo fii enu kan IYO ( SALT ) nii ojo yii kii oun Gbogbo lema lo Deede funwon .

Ògún ologun koni jẹ tiwa lagbara ọlọhun


Ọlọrun koni jeki afi ọwọ ara wa se ara wa

Ki Olorun siju anu wo gbogbo wa 

GBIYANJU KO NI  IWE 

ASIRI IRAWO EDA LOWO

GBÌYÀNJÚ LATI SE ÀWÁRÍ ARA-RE KII OMABA WÁYÉ ASÁN

ÌLÚ TÀBÍ ÀDÚGBÒ GBÍGBÉ FUN GBOGBO IRAWỌ 💯

 ÌLÚ TÀBÍ ÀDÚGBÒ GBÍGBÉ FUN GBOGBO IRAWỌ 💯 

Odara kii amò ilu tabi agbegbe ti odara fún ipin ati iseda irawo wa nitori kii amaba waye bíi aláìsí bẹ sini kii amaba di ẹni ẹyin kii ùn se gbogbo ikan náà níí ota fii ùn dáwà láàmú besini kii ùn se gbogbo ikan níí ogun ìdílé 

Ejeki amo ilu ti odara fún ipin irawo wa gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ; 

       IBUGBE IRAWO INA

Ejeki abere Lori irawo ina pupo ninu awon iseda yii Agaga awontii wonbii nii Ojo Monday orowon kii unduro lojukan pupo ninu won je Akiikanju wonsi ma ungba ero ikan nlala.

        ILU TI WỌN LÈ GBÉ

Odara kii  wọn magbe ilu  tabi agbegbe ti Oke posi (mountain) wọn tún lẹgbẹ ilu tabi Adugbo tii Afefe waa daada  kii wongbiyanju lati jekii igi wanii Ile tiwonba Kọ fún arawọn  nitoripe Afefe aleje oluran lowo fun wọn

             PẸLU ÀFIKÚN

Iseda won ikan giga giga nii wọn má ungba lero ju

 Iseda yii saba má  ùn ló ikan pupa sugbon wonkii un mọ  elomiran ninu won ma un mu Oti kii unse ebiwon bikii se iseda irawo won.


        IBUGBE IRAWO AFEFE

Oba irawo nii irawo yii je kosi ibiti kole gbe won feran latii maase ibere daada wonsi je eyankan tii oma ùn beru pupo ninu won kii un sábà ma un gbagbo pe eyankan wanii idi Oro won nitoripe isada won nii Agbara gan wonje oloju Anu 

Bii wonba unparo Ifaseyin die die ama waye funwon

        ÌLÚ TÍ  TIWONLEGBE

Iseda yii koferan Oru, beeni Wonko feran idoti 

Kosi ilu tii Afefe kolegbe sugbon odara kii irawo yii maa gbe ilu tabi Adugbo tii Omi posi. Daada.


         IBUGBE IRAWO OMI

Kosi Eda Alaye tii oleba irawo yii see ota nitori pataki wonpo lawujo 

      ÌLÚ TÍ TIWONLEGBE

Odara fun irawo yii komagbe Adugbo tii Omi tabi Alafia ma nwa daada nitoripe Omi kii unse ota eyankankan bii Oni irawo Omi ba ungbe ilu tabi Adugbo tii Omi tabi Alafia ba ùn wa odidandan kii irawo ati Ogo ee matesiwaju 

Diẹ ninu awọn  onirawo yii elegbe niwon egbe bii.

Omo Omi

Emere Omi

Iranse Aje

Alaragbo

Ati Bebe lo.

       IBUGBE  IRAWO ERUPE

Odarakii irawo yii magbe ibiti  Ero baapo daada nitoripe kosi eniti olemo iwa iru irawo yii tan

Irawo yìí féràn ilu ti tabi agbegbe ti kii ba ùn da nítorí pé kii ògo ati arisiki ee lè tètè tẹ lọwọ

 Die Lara  awon Obinrin irawo yii Je elegbe bii 

Iranse Àjé

Igi Aje

Omi Anu

Omi àjé

       ÌLÚ TÍ TIWONLEGBE

Ilu tabi Adugbo tii awon eyan ba Saba maun posi nii odaraju fun irawo won nitori pe àjé kii ùn fẹ kii gbogbo agbegbe tí òun bawa ba dull.

Pẹlu pẹlú àwọn tí wọn ùn ló ipin iseda irawo erupe funfun

Fun Amonran Lori Irawo eda ABI Lati mo Irawo Re 

AWON AWO(COLOR) TODARA FUN IRAWO KOOKAN 💯

AWON AWO(COLOR) TODARA FUN IRAWO KOOKAN 💯 

Odara fun irawo kookan komo iru aawo toba irawo remu nitori ose koko si igbesi aye wa gegebi aso wiwo, tabi oda ikunle ati awon nkan Miran 

IRAWO OMI

1_FUNFUN

2_GREEN

3_OMI ARO


IRAWO INA

1_ASO PUPA

2_GOLDEN COLOR

3_GREEN TABI YELLOW


IRAWO IYEPE

1_BROWN

2_GREEN

3_PURPLE

4_RED/CREAM


IRAWO AFEFE

1_ASH

2_YELLOW

3_WHITE

4_PURPLE

Odara ki Olukaluku mo nipa irawo re papa julo nipa aso wiwo, eewo,Sara,ojo orire,asiko gbigba adua pelu awon nkan Miran toba irawo re mu nitori ki nkan lema lo Dede  fun e ninu aye opolopo loti kosi inu wahala nitori wipe ounse nkan tioba irawo remu 

Asima nko sinu wahala lati ara aso ibora nitori osaba man fa ala buruku ti yio siko elomiran sinu wahala 

Ema bami kalo 


OKUNFA ALA BURUKU ATI ALAKALA NIPA ASO WIWO SUN FUN GBOGBO IRAWO


1. IRAWO AFEFE. kodara ki irawo yi mawo aso aso pupa (red),alawo ewe(green),tiwon bafesun lale. Aso todara ju fun irawo yi lati mawosun ni ASO FUNFUN


2. IRAWO INA. kodara ki irawo yi mawo aso tobati lagun si sun (sweat),aso toba doti(dirty)sun,aso toba fi se ise (working cloth),kodara kiwon mawo aso alarabanra sun


3. IRAWO IYEPE. awon aso tikodara fun irawo yi lati mawo sun ni aso dudu,aso brown,aso tiwon fi ni ibalopo,aso okunkun 


4. IRAWO OMI. kodara ki irawo yi mawo aso Ankara sun,aso yellow,aso dudu 

Kise gbogbo alakala lowaye lati owo ota,aso wiwo sun tabi bibora manfa alakala fun onirawo kookan

Ọlọrun koni jeki afi ọwọ ara wa se ara wa

Ki Olorun siju anu wo gbogbo wa 

GBIYANJU KO NI  IWE 

ASIRI IRAWO EDA LOWO

GBÌYÀNJÚ LATI SE ÀWÁRÍ ARA-RE KII OMABA WÁYÉ ASÁN


AWON AKANSE ETO AGBARA TODAJU 💯

AWON AKANSE ETO AGBARA TODAJU 💯 


ETO IFE OKUNRIN ATI OBINRIN

Alubosa Nla Funfun Kan 

Paper Funfun die 

Iyo Didi Die

Odo ti kigbe(River)

Ao ko Oruko Ololufe Mejeji sinu paper Funfun yi ti ko ni Oruko Iya won ninu(Mother  name Requires)ao tibo inu Alubosa,ao fi Iyo die si,ao we ni Owu dudu ati funfun ti ko ni han mo,ao lo ri mole si egbe Odo ti kigbe Opari

Ise yi daju pupo,eni ti aba se ise yi fun,kole fi wa sile rara,Sugbo e je ka beru Olorun,Nitori awa Okunrin Oloju komo lo


IFE TODAJU

Ao fi abere gun atanpako owo wa ao te eje re jade

Ao wa fi ko oruko MALAIKA Yi (RAMPEL) Si Ara eyin adie ibile pelu oruko obirin yen

Ti a ba tise eyin jina ni ooo A o pe oruko yi nigba meje si eyin adie yi pelu adura iferan Odaju...obirin na koni fi o sile mo lailai.

Akiyesi:-mase ise yi fun obirin ti o ko ni fe sile ooo

 ISEGUN OTA

Ti o Bari pe ota kan gbogun tio...gbawe ojo kan ki o ka psalm 10 nigba meje Oruko Malaika nigba meje JARATA AJAJAMOMIN

Ao ka ni aro,osan,ati ale Odaju ao segun awon ota na


 OJURERE ATI ANU

Ao fi omi agbon gbo ewe rerinkomi ati ewe owu akese

Ao wa da sinu CREAM JET

ao tan abela bulu (blue candle) sidi re ao pe oruko mimo yi si ELI LAHA BAHA

pelu psalm 19 nigba meje si Ao fi abela na sile KO joku odaju...a o ma fi para


 ISEGUN ALAROKA

Ao ka psalm 3,35,22,109

Sinu omi iwe

Ao gbawe ojo kan se adura yi Ao wa lo fi omi na we...alaroka yoo tuka

 ISEGUN ADITE TOLAGBARA

Ao wa ka psalm 46, 109, Isaiah 47 ao ka ni osan gangan ni ago kan tabi oru

Ao wa ma da oruko awon Ota re si.. Olorun yoo na won legbe


 ASIRI BIBO

Ao ma pe oruko mimo Yi nigba 70times Lojumo ELOHIM Odaju asiri wa yoo bo

 ISEGUN EJO KOTU

Ao ma pe oruko mimo Yi nigba 71times

JAJI JAILA AKABAJAH

Ao si ri ojurere awon adajo Odaju ooo

Mafi oju di eto won yi oo

 IFERAN ARAYE

Ao ma pe oruko mimo yi Nigba meje sinu perfume eyikeyi...wa ri bi ojo ife yoo se ro le o Lori JANTALIKOKO ELI HAL 7times ao wa ka psalm 24 si nigba kan 1 sinu odaju pa

 ISEGUN ALAKALA

igba idemu 

Ao bu omi sinu re

Ao ka psalm 7 7times A o wa gbe si iri moju,A o lo gbe omi yi ni idaji laisoro si enikeni ao wa gbemu. odaju koni si alakala mo.

 ABO OLORUN

ao pe oruko mimo yi

Nigba meta pere

ELOI ELOI ELOI

ao wa ka psalm 20 nigbaMeta ni Dede ago mejila osan Ao ma se ni ekan lose

 IBUKUN TODAJU

Ti oda owo money 

Ba da eyan Gbiyanju Ase oro yi

JEHOVAH SHALLOH 

JEHOVAH JIREH

ADONIS JEHOVAH

SALLAH JEHOVAH

NUN-JAH-SANATH

ITAMI-SELLAH


ELEYI NI ASIRI IMULE ARINURODE AWON AGBALAGBA TODAJU

Egbo tude idi meje, Aidan onigun meje, Omo olongbo ti koiti laju,Odidi atare meta,Epo obo topo dada, Akuko adie kan,Igba onikoko, Opon ifa ti wonfi igi iroko gben,Ape ijoogun tuntun,Seere nla kan, 

Ose dudu, Eso laa mejeji oojo,Ewe ajeobale oojo,Ao pa olongbo yen,ao wa fi eweajeobale tele ape,ao gbe olongbo naa lee lori ao ko egbo tude si ao ko Aidan si ao ko

atare meta yen si ao ko epo obo topo si ao pa pepe kato kosi,ao ko eso laa mejeji si ao tun wafi ewe ajeobale boo lori dada pada. Ao fi epo pupa yi aro kaa, ao jo,tia ba jotan ao lo kunna dada,ao wa da ebu na sori opon ifa ao fi te odu ifa merindinlogun si, ao daniyan ohun ti abafe si. Ao pin si ona meta ao po ida kan mo ose dudu ao ko sinu igba,onikoko yen. a o wa pa Akuko Adie kan togbo dada ao roo eje re sinu ose yen,ao fi owo po papo,ao da ebu ona meji toseku papo ao ro sinu ado seere yen ao fi eje adie toseku yen boo seere yen ao le iye igbaaya re mo seere yen Lara,ao gbe

Igba ose yen ati ebu inu seere yen sinu aso funfun otooto. Ao gbe sinu apoti tabi cupboard wa tori oju meji kogbodo rimon,ao gbe pamo fun ojo meje,lehin naa ao wa se sarare,ao ma fi akara elepo pupa tabi ekuru funfun see saara re lojojumo fun ojo meje yen lehin ojo keje ao bere lilore.

 LILO RE

Ao ma fi ose yen we lalale ti agogo mewa bati koja, Ao ma fi ebu inu seere naa fo eko tutu mu larolaro

kato soro si enikeni

 NOTE

Obinrin kogbodo loo imule yio,toripe oni ewu fun obinrin ooo.

Ise gidi ni ise osi daju dada moti gbiyanju re laimoye. Kosi nti amu waye losi nti amu lo orun. 


LILO EWE EWURO FUN ISE/OSE ANU NI ORISIRISI ONA TOSI CONFIRM GIDI 100%

ISE ANU.

Ewe ewuro oojo ao gun mose dudu ao fi epo pupa,iyo ati oyin po,ao ko sinu fitila oloju kan ao ti abela funfun kan bo larin ao ma tan ina si ti a ba ti fe lo we ose na,ao ma fi owo pa ina leyin iwe


ISE ANU.

Omundun ewe ewuro oojo, ewe ola, epo obo, kafura pelebe packet kan, ose dudu, ao da osun, oyin ati ori mo omi agbon ao fi po ose na, ao ko sinu ike funfun wiwe laro


Omundun ewe ewuro ojoo, kanfura pelebe packet meta,ao gun mejeji papo mo ose dudu ao ko sinu ike funfun wiwe laro.

         

ISE ANU.

A o fi ori olongbo ti o ni irun tele ape,a o da Ata ijosi le Lori,a o fi ewe ewuro oojo bo mole,a o fi atare kan le Lori,a o Jo,a o ma fi epo pupa la le,a o ma fi oti lo laro. Gbogbo awon ise yi daju gidi walai


CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯

 CONNECTION CLIENT SOAP GEE BOY 💯  Ewe Omisinmisin ti amo si eso oju Olohungbo Oojo tuntun die,ao fo Odidi eyin Ororo ibile ti o mo dada 1k...